Download Audio + Lyrics He has come by Elubaji Daniel

He has come is a spirit filled song by young rising gospel artist, Elubaji Daniel
He got the inspiration from the Bible which make the song so genuine.
stream, Download & Stay Blessed
LYRICS
Lead: Oba Hezekiah, eni to nse’fe olorun
Woli Isaiah la ran, lati jise iku fun,
(wipe) oba pack ur load o, niwoyi ola iku lo ma ku,
Tete ko will re,
Resp: To ba ti dola, o ma ku,
Lead: Ni kete ti woli lo, Oba sare to Olorun re lo,
O ba olorun re soro, o ni b’a se jo so ko l’eyi,
No be say pe I proud o, emi o ni ku lola
Agbonrin mi ti sin,
Resp: Ojo iku mi ti ye,
Lead: Instantly l’Olorun gbo, oni woli Isaiah pada,
So fun pe, a ti fi k’ojo t’o fe lo nile aiye,
Lekese lolorun gbo, O ni woli pada lo ba,
Ati fi 15years
Resp: M’ojo to fe lo nile aiye.
Lead: Opo Safafati, Iwo sa lo dide,
Resp: Nigbati ireti pin,
Lead: Lazaru to ku lojosi, iwo lo ji dide,
(Mod) Iwo lo ji dide OBAJIPOJOIKUDA
Call: Oba Aladewura/2x
Resp: Ajipojoikuda ti de
Call: Ajipojoiku da/2x
Resp: Oba Aladewura ti de
Lead: O ma ti de o, o ti de
Resp: Oba Aladewura ti de
Lead: O ti mu igbalawa, o ti mu iwosan wa, o ti mu isegun wa
Lead: For those who are dead but living, o ti mu iye wa.
……………………………………..